Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 4:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ kúrò! Ẹ̀yin di aláìmọ́!” ni àwọn ènìyàn ń kígbe sí wọn.“Ẹlọ! Ẹlọ! Ẹ má se fọwọ́ kàn wá!”Àwọn ènìyàn láàrin orílẹ̀ èdè wí pé,“Wọn kì yóò tẹ̀dó síbí mọ́.”

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 4

Wo Ẹkún Jeremáyà 4:15 ni o tọ