Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 3:61-66 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

61. Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọnàti ìmọ̀ búburú wọn sí mi—

62. Ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọsí mi ní gbogbo ọjọ́.

63. Wò wọ́n! Ní jíjòkòó tàbí ní dídìde,wọ́n ń ṣẹlẹ́yà mi nínú orin wọn.

64. Olúwa san wọ́n lẹ́san ohun tí ó tọ́ sí wọnfún ohun tí ọwọ́ wọn ti ṣe.

65. Fi ìbòjú bò wọ́n ní ọkàn,kí o sì fi wọ́n ré.

66. Ni wọ́n lára kí o sì pa wọ́n run pẹ̀lú ìbínú,lábẹ́ ọ̀run Olúwa.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 3