Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 3:54-61 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

54. Orí mi kún fún omi,mo sì rò pé ìgbẹ̀yìn dé.

55. Mo pe orúkọ rẹ, Olúwa,láti ọ̀gbun ìsàlẹ̀ ihò.

56. Ìwọ gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi: “Má ṣe di etí rẹsí igbe ẹ̀bẹ̀ mi fún ìtura.”

57. O wá tòsí nígbà tí mo ké pè ọ́,o sì wí pé, “Má se bẹ̀rù.”

58. Olúwa, ìwọ gba ẹjọ́ mi rò,o ra ẹ̀mí mi padà.

59. O ti rí i, Olúwa, búburú tí a ṣe sí miGbé ẹjọ́ mi ró!

60. Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn,gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi.

61. Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọnàti ìmọ̀ búburú wọn sí mi—

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 3