Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 3:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èmi ni ọkùnrin tí ó rí ìpọ́njúpẹ̀lú ọ̀pá ìbínú.

2. Ó ti lémi jáde ó sì mú mi rìnnínú òkùnkùn ju ti ìmọ́lẹ̀;

3. Nítòótọ́, ó ti yí ọwọ́ padà sí misíwájú àti síwájú sí i ní gbogbo ọjọ́.

4. Ó jẹ́ kí àwọ̀ mi àti ẹran ara mi gbóó sì tún ṣẹ́ egungun mi.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 3