Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú ìparun bá ibimímọ́,ó pa ibi ìpàdé rẹ̀ run. Olúwa ti mú Síónì gbàgbéọjọ́ àṣè àti ọ̀ṣẹ̀ tí ó yàn;nínú ìbínú gbígbóná rẹ̀ ni ó runọba àti olórí àlùfáà.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:6 ni o tọ