Làìní àánú ni Olúwa gbéibùgbé Jákọ́bù mì;nínú ìrunú rẹ̀ ni ó wóibi gíga ọmọbìnrin Júdà lulẹ̀.Ó ti mú ìjọba àti àwọn ọmọ aládé ọkùnrinlọ sínú ilẹ̀ ní àìlọ́wọ̀.