Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ọ̀nà tí ó wọ Ṣíónì ń sọ̀fọ̀,nítorí kò sẹ́ni tí ó wá láti jọ́sìn.Ẹnu bodè pátapáta ni ó dahoro,àwọn Olórí àlùfáà ibẹ̀ kérora,àwọn ọ̀dọ́bìnrin rẹ̀ sì ń kẹ́dùn,òun gan-an wà pẹ̀lú ìbànújẹ́ ọkàn.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 1

Wo Ẹkún Jeremáyà 1:4 ni o tọ