Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà náà ni Olúwa sọ fún Mósè pé, “Sọ fún Árónì, ‘Kí ó na ọwọ́ rẹ̀ jáde pẹ̀lú ọ̀pá sí orí àwọn odò kékèké àti odò ńlá, àti sí orí àwọn àbàtà kí ó sì mú àwọn ọ̀pọ̀lọ́ gòkè wá sí ilẹ̀ Íjíbítí.’ ”

Ka pipe ipin Ékísódù 8

Wo Ékísódù 8:5 ni o tọ