Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ìgbà tí Fáráò bá sọ fún un yín pé, ‘Ẹ ṣe iṣẹ́ ìyanu kan,’ sọ fún Árónì ní ìgbà náà pé, ‘Mú ọ̀pá rẹ kí ó sì sọ ọ́ sílẹ̀ níwájú Fáráò,’ yóò sì di ejò.”

Ka pipe ipin Ékísódù 7

Wo Ékísódù 7:9 ni o tọ