Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹja inú odò Náìlì sì kú, odò náà ń rùn gidigidi tí ó fi jẹ́ pé àwọn ará Éjíbítì kò le è mu omi inú rẹ̀. Ẹ̀jẹ̀ sì wà ni ibi gbogbo ni ilẹ̀ Éjíbítì.

Ka pipe ipin Ékísódù 7

Wo Ékísódù 7:21 ni o tọ