Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 7:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè àti Árónì sí ṣe gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún wọn. Ó gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè ni ìwájú Fáráò àti àwọn ìjòyè rẹ̀, ó sì lu omi odò Náìlì, omi odò náà sì yípadà sí ẹ̀jẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 7

Wo Ékísódù 7:20 ni o tọ