Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 5:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò sí dáhùn wí pé, “Ọ̀lẹ niyín, ọ̀lẹ! Èyí ni ó mú kí ẹ̀yin máa sọ ni ìgbà gbogbo pé, ‘Ẹ jẹ́ kí a lọ, kí a sì rúbọ sí Olúwa.’

Ka pipe ipin Ékísódù 5

Wo Ékísódù 5:17 ni o tọ