Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò fún àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni koríko gbígbẹ, ṣíbẹ̀ wọn sọ fún wa pé, ‘Ẹ ṣe bíríkì!’ Wọ́n na àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ, ṣùgbọ́n ẹ̀bi náà wá láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ.”

Ka pipe ipin Ékísódù 5

Wo Ékísódù 5:16 ni o tọ