Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 4:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Ṣípórà mú ọ̀bẹ òkúta mímú, ó sì kọ ọmọ rẹ̀ ní ilà abẹ́, ó si fi awọ rẹ̀ kan ẹṣẹ̀ Mósè. Ṣípórà sì wí pé, “Ọkọ ẹlẹ́jẹ̀ ni ìwọ jẹ́ sí mi.”

Ka pipe ipin Ékísódù 4

Wo Ékísódù 4:25 ni o tọ