Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè mú ìyàwó rẹ̀ àti àwọn ọmọ rẹ̀, ó kó wọn lé orí i kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ó sì bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò rẹ̀ padà sí Éjíbítì. Ó sì mú ọ̀pa Ọlọ́run sí ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 4

Wo Ékísódù 4:20 ni o tọ