Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè padà sí ọdọ Jẹ́tírò baba ìyàwó rẹ̀, ó sì sọ fún un pé, “Jọ̀wọ́ jẹ́ kí n padà tọ àwọn ènìyàn mi lọ ni ilẹ̀ Íjíbítí láti wò bóyá wọ́n sì wà láàyè ṣíbẹ̀.”Jẹ́tirò sì dáhùn, ó wí pé, “Má a lọ ni àlàáfíà.”

Ka pipe ipin Ékísódù 4

Wo Ékísódù 4:18 ni o tọ