Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè dáhùn ó sì wí pé; “Ṣùgbọ́n bí wọn kò bá gbà mí gbọ́ ń kọ́? Tàbí tí wọn kò fi etí sílẹ̀ láti gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ́nu mi, tí wọn sì wí pé, ‘Olúwa kò farahàn ọ́’?”

Ka pipe ipin Ékísódù 4

Wo Ékísódù 4:1 ni o tọ