Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 37:26-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Kìkì wúrà ni ó fi bo orí rẹ̀, gbogbo ìhà rẹ̀ àti ìwo rẹ̀, ó sì fi ìgbátí wúrà yìí ká.

27. Ó se òrùka wúrà méjì sí ìṣàlẹ̀ ìgbátí náà méjì ní ọ̀kánkán ara wọn láti gbá òpó náà mú láti máa fi gbé e.

28. Ó ṣe òpó igi kaṣíá, ó sì bò wọ́n pẹ̀lú u wúrà.

29. Ó sì tún ṣe òróró mímọ́ ìtasórí àti kìkì òórùn dídùn tùràrí-iṣẹ́ àwọn tí ń ṣe nǹkan olóòórùn.

Ka pipe ipin Ékísódù 37