Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 37:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Igi kaṣíá ní ó fi ṣe pẹpẹ tùràrí náà. Igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rẹ̀ jẹ́ déédé, gígùn rẹ̀ jẹ ìdajì mítà, fífẹ̀ rẹ̀ náà jẹ́ ìdajì mítà àti gíga rẹ̀ sì jẹ́ mítà kan-ìwo rẹ̀ sì jẹ́ bákan náà.

Ka pipe ipin Ékísódù 37

Wo Ékísódù 37:25 ni o tọ