Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 36:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì ṣe òpó igi kasíá mẹ́rin fún-un wọ́n sì bò wọ́n pẹ̀lú wúrà. Wọ́n sì ṣe àwọn ìkọ́ wúrà fún wọn, wọ́n sì gba ihò ìtẹ̀bọ̀ fàdákà mẹ́rin wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 36

Wo Ékísódù 36:36 ni o tọ