Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 36:26-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. ogójì (40) fàdákà ihò ìtẹ̀bọ̀ méjì ní ìṣàlẹ̀ pákó kọ̀ọ̀kan.

27. Wọ́n ṣe pákó mẹ́fà sì ìkángun, ní ìkangun ìhà ìwọ̀ oòrùn Àgọ́ náà,

28. pákó méjì ni wọ́n ṣe sí igun Àgọ́ náà ní ìkangun.

29. Ní igun méjèèjì yìí, pákó méjì ni ó wà níbẹ láti ìdí dé orí rẹ̀ wọ́n sì kó wọ́n sí òrùka kan; méjèèjì rí bákan náà.

30. Wọ́n jẹ́ pákó mẹ́jọ àti fàdákà mẹ́rìn-lélógún ìhò ìtẹ̀bọ̀, méjì wà ní ìṣàlẹ̀ kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Ékísódù 36