Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 36:17-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Wọ́n sì pa àádọ́ta (50) ajábó sí ìsẹ́tí ìkángun aṣọ títa ní apá kan, wọ́n sì tún pa ajábó mìíràn sí ìsẹ́tí ìkángun aṣọ títa ní apá ibòmíràn.

18. Wọ́n ṣe àádọ́ta (50) ìkọ́ idẹ láti so Àgọ́ náà pọ̀ kí o lè jẹ́ ọ̀kan.

19. Wọ́n sì ṣe ìbòrí àwọ àgbò tí a rì ní pupa, àti ìbòrí màlúù odò lórí rẹ̀.

20. Wọ́n ṣe pákó igi kaṣíá tí ó dúró fún Àgọ́ náà.

Ka pipe ipin Ékísódù 36