Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 35:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fi ọgbọ́n kún wọn láti se gbogbo onírúurú iṣẹ́, ti oníṣọ̀nà, ti ayàwòrán, ti aránsọ, ti alásọ aláró, ti elésèé àlùkò, ti òdòdó àti ní ọ̀gbọ̀ dáradára àti ti ahunsọ, gbogbo èyí tí ọ̀gá onísẹ́ ọnà àti ayàwòrán ń ṣe.

Ka pipe ipin Ékísódù 35

Wo Ékísódù 35:35 ni o tọ