Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 34:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Má a sọ́ra kí ẹ má se bá àwọn ènìyàn tí ń gbé ilẹ̀ náà dá májẹ̀mú; nígbà tí wọ́n bá ń se àgbérè tọ òrìsà wọn, tí wọ́n sì rúbọ sí wọn, wọn yóò pè yín, ẹ̀yin yóò sì jẹ ẹbọ wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 34

Wo Ékísódù 34:15 ni o tọ