Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 32:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè rí i pé àwọn ènìyàn náà kòṣe e ṣàkóso àti pé Árónì ti sọ wọ́n di aláìlákóṣo láàrin àwọn ọ̀ta tí ó dìde sí wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 32

Wo Ékísódù 32:25 ni o tọ