Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 32:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

È é ṣe tí àwọn ará Éjíbítì yóò ṣe wí pé, ‘Nítorí ibi ni ó ṣe mọ̀ ọ́ mọ̀ mú wọn jáde, láti pa wọ́n ní orí òkè àti láti gbá wọn kúrò lórí ayé’? Yípadà kúrò nínú ìbínú rẹ tí ó múná, yí ọkàn padà, kí o má sì ṣe mú ìparun wá sórí àwọn ènìyàn rẹ.

Ka pipe ipin Ékísódù 32

Wo Ékísódù 32:12 ni o tọ