Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 31:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Olúwa parí ọ̀rọ̀ ṣíṣọ fún Mósè lórí òkè Ṣínáì, ó fún-un ní òkúta wàláà ẹ̀rí méjì, okuta wàláà òkúta tí a fi ìka Ọlọ́run kọ.

Ka pipe ipin Ékísódù 31

Wo Ékísódù 31:18 ni o tọ