Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 30:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì yóò sì máa ṣe ètùtù sórí àwọn ìwo rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan lọ́dún. Óun yóò sì máa ṣe ètùtù ọdọọdún yìí pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ètùtù fún ìran tó ń bọ̀. Mímọ́ jùlọ ni sí Olúwa.”

Ka pipe ipin Ékísódù 30

Wo Ékísódù 30:10 ni o tọ