Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì wí fún Ọlọ́run pé, “Bí mo bá tọ̀ àwọn ará Ísírẹ́lì lọ ti mo sì sọ fún wọn pé, ‘Ọlọ́run àwọn baba yín ni ó rán mi sí i yín,’ tí wọ́n sì béèrè lọ́wọ́ mi pé, ‘Kí ni orúkọ rẹ̀?’ Kí ni èmi yóò sọ fún wọn ní ìgbà náà?”

Ka pipe ipin Ékísódù 3

Wo Ékísódù 3:13 ni o tọ