Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 29:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò sì mọ̀ pé èmi ni Olúwa Ọlọ́run wọn, ẹni tí ó mú wọn jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì wá, nítorí kí èmi lè máa gbé àárin wọn. Èmi ni Olúwa Ọlọ́run wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 29

Wo Ékísódù 29:46 ni o tọ