Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 29:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún ìrandíran tó ń bọ̀, ni ẹ ó máa ṣe ẹbọ sísun nígbà gbogbo ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ níwájú Olúwa. Níbẹ̀ èmi yóò pàdé yín, èmi yóò sì bá a yín sọ̀rò;

Ka pipe ipin Ékísódù 29

Wo Ékísódù 29:42 ni o tọ