Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 29:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ara ìyẹ̀fun aláìwú dídùn, ṣe àkàrà àti àkàrà tí a pò pẹ̀lú òróró, àti àkàrà fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ aláìwú tí a da òróró sí.

Ka pipe ipin Ékísódù 29

Wo Ékísódù 29:2 ni o tọ