Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 29:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò sì gé àgbò náà sí wẹ́wẹ́, ìwọ yóò sì fọ inú àti àwọn ẹsẹ̀ rẹ̀, ìwọ yóò sì tò wọ́n pẹ̀lú orí rẹ̀ lé ara wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 29

Wo Ékísódù 29:17 ni o tọ