Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 29:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o mú gbogbo ọ̀rá tí ó yí inú ká, èyí tí ó bo ẹ̀dọ̀ àti ìwé méjèèjì pẹ̀lú ọ̀rá tí ó wà lára wọn, ìwọ yóò sì sun wọ́n lórí pẹpẹ.

Ka pipe ipin Ékísódù 29

Wo Ékísódù 29:13 ni o tọ