Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 26:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún ti ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà, ìwọ yóò ṣe aṣọ títa aláró, elésèé àlùkò, ti òdódó àti ti ọ̀gbọ̀ olókùn wíwẹ́ tí a fi iṣẹ́ abẹ́rẹ́ ṣe.

Ka pipe ipin Ékísódù 26

Wo Ékísódù 26:36 ni o tọ