Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 26:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ yóò si ṣe aṣọ ìgélé aláró àti elése àlùkò, àti òdòdó, àti ògbọ̀ olókùn wẹ́wẹ́ tíí ṣe ọlọ́nà, pẹ̀lú ti àwọn kérúbu ni kí á ṣe é.

Ka pipe ipin Ékísódù 26

Wo Ékísódù 26:31 ni o tọ