Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 23:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣe àjọ̀dún ìkórè pẹ̀lú èso àkọ́so ọ̀gbìn oko rẹ.“Ṣe àjọ̀dún àkójọ oko rẹ ní òpin ọdún, nígbà tí ìwọ bá kó irè oko rẹ jọ tan.

Ka pipe ipin Ékísódù 23

Wo Ékísódù 23:16 ni o tọ