Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣe àjọ̀dún àkàrà àìwú; jẹ àkàrà ti kò ní ìwúkàrà fún ọjọ́ méje, bí mo ṣe pàṣẹ fún ọ. Ṣe èyí ní àkókò tí a ti yàn ní oṣù Ábíbù, nítorí ni oṣù yìí ni ìwọ jáde kúrò ni ilẹ̀ Éjíbítì.“Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ wá sí iwájú mi ní ọwọ́ òfo.

Ka pipe ipin Ékísódù 23

Wo Ékísódù 23:15 ni o tọ