Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 22:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí iná bá ṣẹ́ tí ó kán lu igbó tí ó sì jó àká ọkà tàbí gbogbo oko náà, ẹni tí iná ṣẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀ yóò san ohun tí ìná ti ó ṣẹ́ jó padà.

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:6 ni o tọ