Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ọkùnrin kan bá ń bọ́ ẹran ọ̀sìn rẹ̀ lórí pápá tàbí nínú ọgbà àjàrà, tí ó sì jẹ́ kí ó lọ jẹ nínú oko ẹlòmíràn, a ó mú kí ó san ohun ti ẹran rẹ̀ jẹ padà pẹ̀lú èyí tí ó dára jù nínú oko tàbí nínú ọgbà rẹ̀ (ẹlòmíràn padà fún un).

Ka pipe ipin Ékísódù 22

Wo Ékísódù 22:5 ni o tọ