Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 20:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Ṣùgbọ́n mo ń fi ìfẹ́ hàn sí ẹgbẹ̀rún ìran nínú àwọn tí ó fẹ́ mi tí wọ́n sì ń pa òfin mi mọ́.

7. “Ìwọ kò gbọdọ̀ pe orúkọ Olúwa Ọlọ́run rẹ ní asán, nítorí Olúwa kì yóò ka àwọn tí ó ń pe orúkọ rẹ̀ ní asán bí aláìlẹ́ṣẹ̀ ní ọ̀run.

8. “Rántí ọjọ́ ìsinmi kí o sì yà á sí mímọ́.

Ka pipe ipin Ékísódù 20