Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 20:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ kò gbọdọ̀ tẹ orí ara rẹ ba fún wọn, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò gbọdọ̀ sìn wọ́n; nítorí Èmi Olúwa Ọlọ́run rẹ, Ọlọ́run owú ni mí, tí ń bẹ ẹ̀sẹ̀ baba wò lára ọmọ láti ìran kìn-ín-ní títí dé ẹ̀kẹrin nínú àwọn tí ó kórìíra mi.

Ka pipe ipin Ékísódù 20

Wo Ékísódù 20:5 ni o tọ