Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 20:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì sọ fún àwọn ènìyàn náà pé, “Ẹ má bẹ̀rù. Ọlọ́run wá láti dán an yín wò, kí ẹ̀rù Ọlọ́run kí ó lè máa wà ní ara yín, kí ẹ̀yin kí ó má ṣe sẹ̀.”

Ka pipe ipin Ékísódù 20

Wo Ékísódù 20:20 ni o tọ