Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 20:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wí fún Mósè pé, “Ìwọ fúnraàrẹ máa bá wa sọ̀rọ̀, àwa yóò sì gbọ́. Má ṣe jẹ́ kí Ọlọ́run fúnraarẹ̀ kí ó bá wa sọ̀rọ̀, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, àwa yóò kú.”

Ka pipe ipin Ékísódù 20

Wo Ékísódù 20:19 ni o tọ