Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin náà sì lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Nígbà tí ó rí í pé ọmọ náà rẹwà, ó gbé ọmọ náà pamọ́ fún oṣù mẹ́ta.

Ka pipe ipin Ékísódù 2

Wo Ékísódù 2:2 ni o tọ