Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 16:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè tún wí pé, “Ẹ̀yin yóò mọ pé Olúwa ni, nígbà ti ó bá fún un yín ni ẹran ni ìrọ̀lẹ̀ àti gbogbo oúnjẹ ti ẹ̀yin ń fẹ́ ni òwúrọ̀, nítorí kíkún ti ẹ̀yin ń kùn sí i. Ta ni àwa? Ẹ̀yin kò kùn sí àwa, Olúwa ni ẹ̀yin kùn sí i.”

Ka pipe ipin Ékísódù 16

Wo Ékísódù 16:8 ni o tọ