Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi ti gbọ́ kíkun àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Sọ fun wọn, ‘Ní àṣálẹ́, ẹ̀yin yóò jẹ ẹran, àti ni òwúrọ̀ ni ẹ̀yin yóò jẹ oúnjẹ. Nígbà náà ni ẹ̀yin yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.’ ”

Ka pipe ipin Ékísódù 16

Wo Ékísódù 16:12 ni o tọ