Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 15:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọ̀ta ń gbéraga, ó ń wí pé:‘Èmi ó lépa wọn, èmi ó bá wọn.Èmi ó pín ìkógun;Èmi ó tẹ́ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ mi lọ́run lára wọn.Èmi yóò fa idà mi yọ, ọwọ́ mi yóò pa wọ́n run.’

Ka pipe ipin Ékísódù 15

Wo Ékísódù 15:9 ni o tọ