Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 14:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì wí fún Mósè pé, “Na ọwọ́ rẹ sí orí òkun kí omi òkun lè ya padà sórí àwọn ará Éjíbítì, kẹ̀kẹ́ ogun wọn àti sórí ẹlẹ́sin wọn.”

Ka pipe ipin Ékísódù 14

Wo Ékísódù 14:26 ni o tọ