Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 12:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àjòjì ti ó bá ń gbé ní àárin yín ti ó bá fẹ́ kópa nínú àjọ ìrékọjá Olúwa, ni o gbọdọ̀ kọ gbogbo àwọn ọmọkùnrin ilé rẹ̀ ní ìlà; ní ìgbà náà ni ó lè kó ipa gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ tí a bí ní ilẹ̀ náà. Gbogbo àwọn ọmọkùnrin tí a kò bá kọ ní ìlà, wọ́n kò ni jẹ ni ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:48 ni o tọ